Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #32 Translated in Yoruba

يُرِيدُ اللَّهُ أَنْ يُخَفِّفَ عَنْكُمْ ۚ وَخُلِقَ الْإِنْسَانُ ضَعِيفًا
Allahu fe se irorun fun yin; A si seda eniyan ni ole
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا لَا تَأْكُلُوا أَمْوَالَكُمْ بَيْنَكُمْ بِالْبَاطِلِ إِلَّا أَنْ تَكُونَ تِجَارَةً عَنْ تَرَاضٍ مِنْكُمْ ۚ وَلَا تَقْتُلُوا أَنْفُسَكُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ كَانَ بِكُمْ رَحِيمًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e ma se fi eru je dukia yin laaarin ara yin ayafi ki o je owo sise pelu iyonu laaarin ara yin. E ma se para yin. Dajudaju Allahu n je Alaaanu si yin
وَمَنْ يَفْعَلْ ذَٰلِكَ عُدْوَانًا وَظُلْمًا فَسَوْفَ نُصْلِيهِ نَارًا ۚ وَكَانَ ذَٰلِكَ عَلَى اللَّهِ يَسِيرًا
Enikeni ti o ba si se iyen lati fi tayo enu-ala ati lati fi se abosi, laipe A maa mu un wo inu Ina. Irorun si ni iyen je fun Allahu
إِنْ تَجْتَنِبُوا كَبَائِرَ مَا تُنْهَوْنَ عَنْهُ نُكَفِّرْ عَنْكُمْ سَيِّئَاتِكُمْ وَنُدْخِلْكُمْ مُدْخَلًا كَرِيمًا
Ti e ba jinna si awon ese nlanla ti A ko fun yin, A maa pa awon iwa aidaa yin re fun yin, A si maa mu yin wo aye alapon-onle
وَلَا تَتَمَنَّوْا مَا فَضَّلَ اللَّهُ بِهِ بَعْضَكُمْ عَلَىٰ بَعْضٍ ۚ لِلرِّجَالِ نَصِيبٌ مِمَّا اكْتَسَبُوا ۖ وَلِلنِّسَاءِ نَصِيبٌ مِمَّا اكْتَسَبْنَ ۚ وَاسْأَلُوا اللَّهَ مِنْ فَضْلِهِ ۗ إِنَّ اللَّهَ كَانَ بِكُلِّ شَيْءٍ عَلِيمًا
E ma se jerankan ohun ti Allahu fi s’oore ajulo fun apa kan yin lori apa kan. Ipin (esan) n be fun awon okunrin nipa ohun ti won se nise, ipin (esan) si n be fun awon obinrin nipa ohun ti won se nise. Ki e si toro lodo Allahu alekun oore Re. Dajudaju Allahu n je Onimo nipa gbogbo nnkan

Choose other languages: