Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Maeda Ayahs #87 Translated in Yoruba

وَإِذَا سَمِعُوا مَا أُنْزِلَ إِلَى الرَّسُولِ تَرَىٰ أَعْيُنَهُمْ تَفِيضُ مِنَ الدَّمْعِ مِمَّا عَرَفُوا مِنَ الْحَقِّ ۖ يَقُولُونَ رَبَّنَا آمَنَّا فَاكْتُبْنَا مَعَ الشَّاهِدِينَ
Nigba ti won ba gbo ohun ti A sokale fun Ojise naa, o maa ri eyinju won ti o maa damije nitori ohun ti won ti mo ninu ododo. Won a si so pe: "Oluwa wa, a gbagbo ni ododo, ko wa mo ara awon olujerii (ododo)
وَمَا لَنَا لَا نُؤْمِنُ بِاللَّهِ وَمَا جَاءَنَا مِنَ الْحَقِّ وَنَطْمَعُ أَنْ يُدْخِلَنَا رَبُّنَا مَعَ الْقَوْمِ الصَّالِحِينَ
Ki ni o maa di wa lowo ti a o fi nii gbagbo ninu Allahu ati ohun ti o de ba wa ninu ododo (iyen, al-Ƙur’an), ti a si n jerankan pe ki Oluwa fi wa sinu awon eni-ire
فَأَثَابَهُمُ اللَّهُ بِمَا قَالُوا جَنَّاتٍ تَجْرِي مِنْ تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا ۚ وَذَٰلِكَ جَزَاءُ الْمُحْسِنِينَ
Nitori naa, nitori ohun ti won so, Allahu san won ni esan pelu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Iyen si ni esan fun awon oluse-rere
وَالَّذِينَ كَفَرُوا وَكَذَّبُوا بِآيَاتِنَا أُولَٰئِكَ أَصْحَابُ الْجَحِيمِ
Awon t’o si sai gbagbo, ti won pe awon ayah Wa niro, awon wonyen ni ero inu ina Jehim
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا لَا تُحَرِّمُوا طَيِّبَاتِ مَا أَحَلَّ اللَّهُ لَكُمْ وَلَا تَعْتَدُوا ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْمُعْتَدِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e ma se so awon nnkan daadaa ti Allahu se ni eto fun yin di eewo. E si ma se tayo enu-ala. Dajudaju Allahu ko feran awon olutayo enu-ala

Choose other languages: