Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #195 Translated in Yoruba

وَاقْتُلُوهُمْ حَيْثُ ثَقِفْتُمُوهُمْ وَأَخْرِجُوهُمْ مِنْ حَيْثُ أَخْرَجُوكُمْ ۚ وَالْفِتْنَةُ أَشَدُّ مِنَ الْقَتْلِ ۚ وَلَا تُقَاتِلُوهُمْ عِنْدَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ حَتَّىٰ يُقَاتِلُوكُمْ فِيهِ ۖ فَإِنْ قَاتَلُوكُمْ فَاقْتُلُوهُمْ ۗ كَذَٰلِكَ جَزَاءُ الْكَافِرِينَ
E pa won nibikibi ti owo yin ba ti ba won. Ki e si le won jade kuro nibi ti won ti le yin jade. Ifooro le ju pipa lo. E ma se ba won ja ni Mosalasi Haram afi igba ti won ba ba yin ja ninu re. Nitori naa, ti won ba ba yin ja, e ba won ja. Bayen ni esan awon alaigbagbo
فَإِنِ انْتَهَوْا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَحِيمٌ
Ti won ba si jawo (ninu iborisa), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
وَقَاتِلُوهُمْ حَتَّىٰ لَا تَكُونَ فِتْنَةٌ وَيَكُونَ الدِّينُ لِلَّهِ ۖ فَإِنِ انْتَهَوْا فَلَا عُدْوَانَ إِلَّا عَلَى الظَّالِمِينَ
E gbogun ti won titi ko fi nii si ifooro (iborisa) mo. Esin ’Islam yo si wa (ni ominira) fun Allahu. Nitori naa, ti won ba jawo (ninu iborisa), ko si ogun mo ayafi lori awon alabosi
الشَّهْرُ الْحَرَامُ بِالشَّهْرِ الْحَرَامِ وَالْحُرُمَاتُ قِصَاصٌ ۚ فَمَنِ اعْتَدَىٰ عَلَيْكُمْ فَاعْتَدُوا عَلَيْهِ بِمِثْلِ مَا اعْتَدَىٰ عَلَيْكُمْ ۚ وَاتَّقُوا اللَّهَ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ مَعَ الْمُتَّقِينَ
Osu owo fun osu owo. Awon nnkan owo si ni (ofin) igbesan. Nitori naa, enikeni ti o ba tayo enu-ala si yin, e gb’esan itayo enu-ala lara re pelu iru ohun ti o fi tayo enu-ala si yin. E beru Allahu. Ki e si mo pe dajudaju Allahu n be pelu awon oluberu (Re)
وَأَنْفِقُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ وَلَا تُلْقُوا بِأَيْدِيكُمْ إِلَى التَّهْلُكَةِ ۛ وَأَحْسِنُوا ۛ إِنَّ اللَّهَ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ
E nawo fun ogun esin Allahu. Ki e si ma se fi owo ara yin fa iparun (nipa sisa fun ogun esin). E se rere. Dajudaju Allahu nifee awon oluse-rere

Choose other languages: