Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Anaam Ayahs #163 Translated in Yoruba

إِنَّ الَّذِينَ فَرَّقُوا دِينَهُمْ وَكَانُوا شِيَعًا لَسْتَ مِنْهُمْ فِي شَيْءٍ ۚ إِنَّمَا أَمْرُهُمْ إِلَى اللَّهِ ثُمَّ يُنَبِّئُهُمْ بِمَا كَانُوا يَفْعَلُونَ
Dajudaju awon t’o ya esin won si otooto, ti won si di ijo-ijo, iwo ko ni nnkan kan se po pelu won. Oro won si n be ni odo Allahu. Leyin naa, O maa fun won ni iro ohun ti won n se nise
مَنْ جَاءَ بِالْحَسَنَةِ فَلَهُ عَشْرُ أَمْثَالِهَا ۖ وَمَنْ جَاءَ بِالسَّيِّئَةِ فَلَا يُجْزَىٰ إِلَّا مِثْلَهَا وَهُمْ لَا يُظْلَمُونَ
Enikeni t’o ba mu ise daadaa wa, (esan) mewaa iru re l’o maa wa fun un. Enikeni t’o ba si mu ise aburu wa, A o nii san an ni esan ayafi iru re. A o si nii sabosi si won
قُلْ إِنَّنِي هَدَانِي رَبِّي إِلَىٰ صِرَاطٍ مُسْتَقِيمٍ دِينًا قِيَمًا مِلَّةَ إِبْرَاهِيمَ حَنِيفًا ۚ وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
So pe: “Dajudaju Oluwa mi ti fi ona taara (’Islam) mo mi, esin t’o fese rinle, esin (Anabi) ’Ibrohim, oluduro-deede-ninu-esin, ko si si ninu awon osebo.”
قُلْ إِنَّ صَلَاتِي وَنُسُكِي وَمَحْيَايَ وَمَمَاتِي لِلَّهِ رَبِّ الْعَالَمِينَ
So pe: "Dajudaju irun mi, eran (pipa) mi, isemi aye mi ati iku mi n je ti Allahu, Oluwa gbogbo eda
لَا شَرِيكَ لَهُ ۖ وَبِذَٰلِكَ أُمِرْتُ وَأَنَا أَوَّلُ الْمُسْلِمِينَ
Ko si akegbe fun Un. Iyen ni Won pa lase fun mi. Emi si ni eni-akoko awon musulumi (ni asiko temi)

Choose other languages: