Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #72 Translated in Yoruba

وَلَهَدَيْنَاهُمْ صِرَاطًا مُسْتَقِيمًا
Ati pe dajudaju Awa iba to won si ona taara
وَمَنْ يُطِعِ اللَّهَ وَالرَّسُولَ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الَّذِينَ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيْهِمْ مِنَ النَّبِيِّينَ وَالصِّدِّيقِينَ وَالشُّهَدَاءِ وَالصَّالِحِينَ ۚ وَحَسُنَ أُولَٰئِكَ رَفِيقًا
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin
ذَٰلِكَ الْفَضْلُ مِنَ اللَّهِ ۚ وَكَفَىٰ بِاللَّهِ عَلِيمًا
Oore ajulo yen maa wa lati odo Allahu; Allahu si to ni Onimo
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا خُذُوا حِذْرَكُمْ فَانْفِرُوا ثُبَاتٍ أَوِ انْفِرُوا جَمِيعًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e mu ohun isora yin lowo, ki e si tu jade s’oju ogun esin nikoniko tabi ki e tu jade ni apapo
وَإِنَّ مِنْكُمْ لَمَنْ لَيُبَطِّئَنَّ فَإِنْ أَصَابَتْكُمْ مُصِيبَةٌ قَالَ قَدْ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيَّ إِذْ لَمْ أَكُنْ مَعَهُمْ شَهِيدًا
Dajudaju o n be ninu yin eni t’o n fa seyin. Ti adanwo kan ba kan yin, o maa wi pe: "Allahu kuku ti se idera fun mi nitori pe emi ko si nibe pelu won

Choose other languages: