Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #71 Translated in Yoruba

وَإِذًا لَآتَيْنَاهُمْ مِنْ لَدُنَّا أَجْرًا عَظِيمًا
Nigba naa, dajudaju Awa iba fun won ni esan nla lati odo Wa
وَلَهَدَيْنَاهُمْ صِرَاطًا مُسْتَقِيمًا
Ati pe dajudaju Awa iba to won si ona taara
وَمَنْ يُطِعِ اللَّهَ وَالرَّسُولَ فَأُولَٰئِكَ مَعَ الَّذِينَ أَنْعَمَ اللَّهُ عَلَيْهِمْ مِنَ النَّبِيِّينَ وَالصِّدِّيقِينَ وَالشُّهَدَاءِ وَالصَّالِحِينَ ۚ وَحَسُنَ أُولَٰئِكَ رَفِيقًا
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin
ذَٰلِكَ الْفَضْلُ مِنَ اللَّهِ ۚ وَكَفَىٰ بِاللَّهِ عَلِيمًا
Oore ajulo yen maa wa lati odo Allahu; Allahu si to ni Onimo
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا خُذُوا حِذْرَكُمْ فَانْفِرُوا ثُبَاتٍ أَوِ انْفِرُوا جَمِيعًا
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e mu ohun isora yin lowo, ki e si tu jade s’oju ogun esin nikoniko tabi ki e tu jade ni apapo

Choose other languages: