Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #124 Translated in Yoruba

يَعِدُهُمْ وَيُمَنِّيهِمْ ۖ وَمَا يَعِدُهُمُ الشَّيْطَانُ إِلَّا غُرُورًا
Esu n sadehun fun won, o si n fi ife-iro sinu okan won. Esu ko si sadehun kan fun won bi ko se etan
أُولَٰئِكَ مَأْوَاهُمْ جَهَنَّمُ وَلَا يَجِدُونَ عَنْهَا مَحِيصًا
Awon wonyen, ina Jahanamo ni ibugbe won; won ko si nii ri ibusasi kan
وَالَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ سَنُدْخِلُهُمْ جَنَّاتٍ تَجْرِي مِنْ تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا أَبَدًا ۖ وَعْدَ اللَّهِ حَقًّا ۚ وَمَنْ أَصْدَقُ مِنَ اللَّهِ قِيلًا
Awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si sise rere, A maa mu won wo inu awon Ogba Idera kan, ti odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re titi laelae. (O je) adehun ti Allahu se ni ti ododo. Ta si ni o so ododo ju Allahu lo
لَيْسَ بِأَمَانِيِّكُمْ وَلَا أَمَانِيِّ أَهْلِ الْكِتَابِ ۗ مَنْ يَعْمَلْ سُوءًا يُجْزَ بِهِ وَلَا يَجِدْ لَهُ مِنْ دُونِ اللَّهِ وَلِيًّا وَلَا نَصِيرًا
Ki i se ife-okan yin, bee ni ki i se ife-okan awon ahlu-l-kitab (ni osuwon idajo orun. Amo,) enikeni ti o ba sise aburu kan, A oo san an ni esan re; ko si nii ri alafeyinti tabi alaranse kan leyin Allahu
وَمَنْ يَعْمَلْ مِنَ الصَّالِحَاتِ مِنْ ذَكَرٍ أَوْ أُنْثَىٰ وَهُوَ مُؤْمِنٌ فَأُولَٰئِكَ يَدْخُلُونَ الْجَنَّةَ وَلَا يُظْلَمُونَ نَقِيرًا
Enikeni ti o ba sise rere, yala okunrin tabi obinrin, onigbagbo ododo si ni, awon wonyen l’o maa wo inu Ogba Idera. A o si nii sabosi eekan koro dabinu fun won

Choose other languages: