Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #48 Translated in Yoruba

أَتَأْمُرُونَ النَّاسَ بِالْبِرِّ وَتَنْسَوْنَ أَنْفُسَكُمْ وَأَنْتُمْ تَتْلُونَ الْكِتَابَ ۚ أَفَلَا تَعْقِلُونَ
Se eyin yoo maa pa awon eniyan l’ase ohun rere, e si n gbagbe emi ara yin, eyin si n ke Tira, se e o se laakaye ni
وَاسْتَعِينُوا بِالصَّبْرِ وَالصَّلَاةِ ۚ وَإِنَّهَا لَكَبِيرَةٌ إِلَّا عَلَى الْخَاشِعِينَ
E wa oore (Allahu) pelu suuru ati irun kiki. Dajudaju o lagbara (lati se bee) ayafi fun awon olupaya (Allahu)
الَّذِينَ يَظُنُّونَ أَنَّهُمْ مُلَاقُو رَبِّهِمْ وَأَنَّهُمْ إِلَيْهِ رَاجِعُونَ
awon t’o mo pe dajudaju awon yoo pade Oluwa won, ati pe dajudaju awon yoo pada si odo Re
يَا بَنِي إِسْرَائِيلَ اذْكُرُوا نِعْمَتِيَ الَّتِي أَنْعَمْتُ عَلَيْكُمْ وَأَنِّي فَضَّلْتُكُمْ عَلَى الْعَالَمِينَ
Eyin omo ’Isro’il, e ranti idera Mi, eyi ti Mo fi sedera fun yin. Dajudaju Emi tun soore ajulo fun yin lori awon eda (asiko yin)
وَاتَّقُوا يَوْمًا لَا تَجْزِي نَفْسٌ عَنْ نَفْسٍ شَيْئًا وَلَا يُقْبَلُ مِنْهَا شَفَاعَةٌ وَلَا يُؤْخَذُ مِنْهَا عَدْلٌ وَلَا هُمْ يُنْصَرُونَ
E beru ojo kan ti emi kan ko nii sanfaani kini kan fun emi kan. A o nii gba isipe kan lowo re.1 A o si nii gba aaro l’owo re. A o si nii ran won lowo.2 awon ayah miiran so pe isipe wa.” Won ni “Itakora niyen.” 123 ati 254 ati surah al-’Ani‘am; 6:51. Amo awon ayah t’o n so pe isipe maa wa lojo Ajinde n so nipa awon majemu ti o wa fun isipe olusipe ati olusipe-fun. Irufe awon ayah naa ni surah al-Baƙorah

Choose other languages: