Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #163 Translated in Yoruba

إِنَّ الَّذِينَ يَكْتُمُونَ مَا أَنْزَلْنَا مِنَ الْبَيِّنَاتِ وَالْهُدَىٰ مِنْ بَعْدِ مَا بَيَّنَّاهُ لِلنَّاسِ فِي الْكِتَابِ ۙ أُولَٰئِكَ يَلْعَنُهُمُ اللَّهُ وَيَلْعَنُهُمُ اللَّاعِنُونَ
Dajudaju awon t’o n daso bo ohun ti A sokale ninu awon eri t’o yanju ati imona, leyin ti A ti se alaye re fun awon eniyan sinu Tira, awon wonyen ni Allahu n sebi le. Awon olusebi si n sebi le won
إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا وَأَصْلَحُوا وَبَيَّنُوا فَأُولَٰئِكَ أَتُوبُ عَلَيْهِمْ ۚ وَأَنَا التَّوَّابُ الرَّحِيمُ
Ayafi awon t’o ronu piwada, ti won se atunse, ti won si safi han ododo, nitori naa awon wonyen ni Mo maa gba ironupiwada won. Emi si ni Olugba-ironupiwada, Asake-orun
إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَمَاتُوا وَهُمْ كُفَّارٌ أُولَٰئِكَ عَلَيْهِمْ لَعْنَةُ اللَّهِ وَالْمَلَائِكَةِ وَالنَّاسِ أَجْمَعِينَ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si ku nigba ti won je alaigbagbo, awon wonyen ni egun Allahu, (egun) awon molaika ati (egun) eniyan patapata n be lori won
خَالِدِينَ فِيهَا ۖ لَا يُخَفَّفُ عَنْهُمُ الْعَذَابُ وَلَا هُمْ يُنْظَرُونَ
Olusegbere ni won ninu re. Nitori naa, A o nii gbe iya fuye fun won. A o si nii fun won ni isinmi (ninu Ina)
وَإِلَٰهُكُمْ إِلَٰهٌ وَاحِدٌ ۖ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الرَّحْمَٰنُ الرَّحِيمُ
Olohun yin, Olohun Okan soso ni. Ko si olohun kan ti ijosin to si ayafi Oun, Ajoke-aye, Asake-orun

Choose other languages: