Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #25 Translated in Yoruba

إِنَّ الَّذِينَ يَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَيَقْتُلُونَ النَّبِيِّينَ بِغَيْرِ حَقٍّ وَيَقْتُلُونَ الَّذِينَ يَأْمُرُونَ بِالْقِسْطِ مِنَ النَّاسِ فَبَشِّرْهُمْ بِعَذَابٍ أَلِيمٍ
Dajudaju awon t’o n sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, ti won n pa awon Anabi lai letoo, ti won tun n pa awon eniyan ti n pase sise eto, fun won ni iro iya eleta-elero
أُولَٰئِكَ الَّذِينَ حَبِطَتْ أَعْمَالُهُمْ فِي الدُّنْيَا وَالْآخِرَةِ وَمَا لَهُمْ مِنْ نَاصِرِينَ
Awon wonyen ni awon ti ise won ti baje ni ile aye ati ni orun. Won ko si nii ri awon oluranlowo
أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ أُوتُوا نَصِيبًا مِنَ الْكِتَابِ يُدْعَوْنَ إِلَىٰ كِتَابِ اللَّهِ لِيَحْكُمَ بَيْنَهُمْ ثُمَّ يَتَوَلَّىٰ فَرِيقٌ مِنْهُمْ وَهُمْ مُعْرِضُونَ
Se o o ri awon ti A fun ni ipin kan ninu Tira, ti A n pe sibi Tira Allahu, ki o le se idajo laaarin won, leyin naa ti ijo kan ninu won n peyin da, ti won si n gbunri
ذَٰلِكَ بِأَنَّهُمْ قَالُوا لَنْ تَمَسَّنَا النَّارُ إِلَّا أَيَّامًا مَعْدُودَاتٍ ۖ وَغَرَّهُمْ فِي دِينِهِمْ مَا كَانُوا يَفْتَرُونَ
Iyen nitori pe dajudaju won wi pe: “Ina ko le jo wa tayo awon ojo t’o lonka.” Ohun ti won n da ni adapa iro si tan won je ninu esin won
فَكَيْفَ إِذَا جَمَعْنَاهُمْ لِيَوْمٍ لَا رَيْبَ فِيهِ وَوُفِّيَتْ كُلُّ نَفْسٍ مَا كَسَبَتْ وَهُمْ لَا يُظْلَمُونَ
Nitori naa, bawo ni (o se maa ri fun won) nigba ti A ba ko won jo ni ojo kan, ti ko si iyemeji ninu re? Ati pe A maa san emi kookan ni esan ohun ti o se nise ni ekun-rere. Won ko si nii sabosi si won

Choose other languages: