Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #151 Translated in Yoruba

وَمَا كَانَ قَوْلَهُمْ إِلَّا أَنْ قَالُوا رَبَّنَا اغْفِرْ لَنَا ذُنُوبَنَا وَإِسْرَافَنَا فِي أَمْرِنَا وَثَبِّتْ أَقْدَامَنَا وَانْصُرْنَا عَلَى الْقَوْمِ الْكَافِرِينَ
Ko si si ohun kan ti won so tayo pe won so pe: "Oluwa wa fori awon ese wa ati aseju wa ninu oro wa jin wa, mu ese wa duro sinsin, ki O si se aranse fun wa lori ijo alaigbagbo
فَآتَاهُمُ اللَّهُ ثَوَابَ الدُّنْيَا وَحُسْنَ ثَوَابِ الْآخِرَةِ ۗ وَاللَّهُ يُحِبُّ الْمُحْسِنِينَ
Nitori naa, Allahu fun won ni esan aye ati daadaa esan orun. Allahu si nifee awon oluse rere
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنْ تُطِيعُوا الَّذِينَ كَفَرُوا يَرُدُّوكُمْ عَلَىٰ أَعْقَابِكُمْ فَتَنْقَلِبُوا خَاسِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele awon t’o sai gbagbo, won maa yi yin lese pada kuro ninu esin. Nigba naa, e maa pada di eni ofo (sinu aigbagbo)
بَلِ اللَّهُ مَوْلَاكُمْ ۖ وَهُوَ خَيْرُ النَّاصِرِينَ
Allahu si ni Alaranse yin. O si loore julo ninu awon alaranse
سَنُلْقِي فِي قُلُوبِ الَّذِينَ كَفَرُوا الرُّعْبَ بِمَا أَشْرَكُوا بِاللَّهِ مَا لَمْ يُنَزِّلْ بِهِ سُلْطَانًا ۖ وَمَأْوَاهُمُ النَّارُ ۚ وَبِئْسَ مَثْوَى الظَّالِمِينَ
A maa fi eru jeje sinu okan awon t’o sai gbagbo nitori pe won ba Allahu wa akegbe, eyi ti ko so eri kan kale fun. Ina si ni ibugbe won; ile awon alabosi si buru

Choose other languages: