Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #46 Translated in Yoruba

وَلَا تَلْبِسُوا الْحَقَّ بِالْبَاطِلِ وَتَكْتُمُوا الْحَقَّ وَأَنْتُمْ تَعْلَمُونَ
E ma da iro po mo ododo, e si ma fi ododo pamo nigba ti eyin mo (ododo)
وَأَقِيمُوا الصَّلَاةَ وَآتُوا الزَّكَاةَ وَارْكَعُوا مَعَ الرَّاكِعِينَ
E kirun, e yo zakah, ki e si dawo te orunkun pelu awon oludawote-orunkun (lori irun)
أَتَأْمُرُونَ النَّاسَ بِالْبِرِّ وَتَنْسَوْنَ أَنْفُسَكُمْ وَأَنْتُمْ تَتْلُونَ الْكِتَابَ ۚ أَفَلَا تَعْقِلُونَ
Se eyin yoo maa pa awon eniyan l’ase ohun rere, e si n gbagbe emi ara yin, eyin si n ke Tira, se e o se laakaye ni
وَاسْتَعِينُوا بِالصَّبْرِ وَالصَّلَاةِ ۚ وَإِنَّهَا لَكَبِيرَةٌ إِلَّا عَلَى الْخَاشِعِينَ
E wa oore (Allahu) pelu suuru ati irun kiki. Dajudaju o lagbara (lati se bee) ayafi fun awon olupaya (Allahu)
الَّذِينَ يَظُنُّونَ أَنَّهُمْ مُلَاقُو رَبِّهِمْ وَأَنَّهُمْ إِلَيْهِ رَاجِعُونَ
awon t’o mo pe dajudaju awon yoo pade Oluwa won, ati pe dajudaju awon yoo pada si odo Re

Choose other languages: