Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #271 Translated in Yoruba

يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا أَنْفِقُوا مِنْ طَيِّبَاتِ مَا كَسَبْتُمْ وَمِمَّا أَخْرَجْنَا لَكُمْ مِنَ الْأَرْضِ ۖ وَلَا تَيَمَّمُوا الْخَبِيثَ مِنْهُ تُنْفِقُونَ وَلَسْتُمْ بِآخِذِيهِ إِلَّا أَنْ تُغْمِضُوا فِيهِ ۚ وَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ غَنِيٌّ حَمِيدٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e na ninu awon nnkan daadaa ti e se nise ati ninu awon nnkan ti A mu jade fun yin lati inu ile. E ma se gbero lati na ninu eyi ti ko dara. Eyin naa ko nii gba a afi ki e diju gba a. Ki e si mo pe dajudaju Allahu ni Oloro, Eleyin
الشَّيْطَانُ يَعِدُكُمُ الْفَقْرَ وَيَأْمُرُكُمْ بِالْفَحْشَاءِ ۖ وَاللَّهُ يَعِدُكُمْ مَغْفِرَةً مِنْهُ وَفَضْلًا ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
Esu n fi osi deru ba yin, o si n pa yin ni ase ibaje sise. Allahu si n se adehun aforijin ati oore ajulo lati odo Re fun yin. Allahu ni Olugbaaye, Onimo
يُؤْتِي الْحِكْمَةَ مَنْ يَشَاءُ ۚ وَمَنْ يُؤْتَ الْحِكْمَةَ فَقَدْ أُوتِيَ خَيْرًا كَثِيرًا ۗ وَمَا يَذَّكَّرُ إِلَّا أُولُو الْأَلْبَابِ
O n fun eni ti O ba fe ni oye ijinle. Eni ti A ba si fun ni oye ijinle, A kuku ti fun un ni oore pupo. Eni kan ko nii lo iranti afi awon onilaakaye
وَمَا أَنْفَقْتُمْ مِنْ نَفَقَةٍ أَوْ نَذَرْتُمْ مِنْ نَذْرٍ فَإِنَّ اللَّهَ يَعْلَمُهُ ۗ وَمَا لِلظَّالِمِينَ مِنْ أَنْصَارٍ
Ohunkohun ti e ba na ni inawo tabi (ohunkohun) ti e ba je ni eje, dajudaju Allahu mo on. Ko si nii si oluranlowo kan fun awon alabosi
إِنْ تُبْدُوا الصَّدَقَاتِ فَنِعِمَّا هِيَ ۖ وَإِنْ تُخْفُوهَا وَتُؤْتُوهَا الْفُقَرَاءَ فَهُوَ خَيْرٌ لَكُمْ ۚ وَيُكَفِّرُ عَنْكُمْ مِنْ سَيِّئَاتِكُمْ ۗ وَاللَّهُ بِمَا تَعْمَلُونَ خَبِيرٌ
Ti e ba safi han awon saraa, o kuku dara. Ti e ba si fi pamo, ti e lo fun awon alaini, o si dara julo fun yin. Allahu si maa pa awon iwa aidaa yin re fun yin. Allahu si ni Alamotan nipa ohun ti e n se nise

Choose other languages: