Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #209 Translated in Yoruba

وَإِذَا تَوَلَّىٰ سَعَىٰ فِي الْأَرْضِ لِيُفْسِدَ فِيهَا وَيُهْلِكَ الْحَرْثَ وَالنَّسْلَ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ الْفَسَادَ
Nigba ti o ba si yise pada, o maa sise kiri lori ile nitori ki o le sebaje sori ile, ki o si le pa nnkan oko ati eran-osin run. Allahu ko si feran ibaje
وَإِذَا قِيلَ لَهُ اتَّقِ اللَّهَ أَخَذَتْهُ الْعِزَّةُ بِالْإِثْمِ ۚ فَحَسْبُهُ جَهَنَّمُ ۚ وَلَبِئْسَ الْمِهَادُ
Ati pe nigba ti won ba so fun un pe: “Beru Allahu.” Igberaga si maa mu un dese. Nitori naa, ina Jahanamo yoo to o (ni esan). Ibugbe naa si buru
وَمِنَ النَّاسِ مَنْ يَشْرِي نَفْسَهُ ابْتِغَاءَ مَرْضَاتِ اللَّهِ ۗ وَاللَّهُ رَءُوفٌ بِالْعِبَادِ
O n be ninu awon eniyan, eni t’o n ta emi ara re lati wa iyonu Allahu. Allahu si ni Alaaanu fun awon erusin (Re)
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا ادْخُلُوا فِي السِّلْمِ كَافَّةً وَلَا تَتَّبِعُوا خُطُوَاتِ الشَّيْطَانِ ۚ إِنَّهُ لَكُمْ عَدُوٌّ مُبِينٌ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e ko s’inu esin ’Islam patapata. Eyin ko si gbodo tele oju-ese Esu. Dajudaju oun ni ota ponnbele fun yin
فَإِنْ زَلَلْتُمْ مِنْ بَعْدِ مَا جَاءَتْكُمُ الْبَيِّنَاتُ فَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ عَزِيزٌ حَكِيمٌ
Nitori naa, ti ese yin ba ye (kuro ninu ’Islam) leyin ti awon eri t’o yanju ti de ba yin, ki e mo pe dajudaju Allahu ni Alagbara, Ologbon

Choose other languages: