Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #192 Translated in Yoruba

وَلَا تَأْكُلُوا أَمْوَالَكُمْ بَيْنَكُمْ بِالْبَاطِلِ وَتُدْلُوا بِهَا إِلَى الْحُكَّامِ لِتَأْكُلُوا فَرِيقًا مِنْ أَمْوَالِ النَّاسِ بِالْإِثْمِ وَأَنْتُمْ تَعْلَمُونَ
Eyin ko gbodo fi eru je dukia yin laaarin ara yin. Eyin ko si gbodo gbe dukia lo ba awon adajo (ni abetele) nitori ki e le fi ese je ipin kan ninu dukia awon eniyan, eyin si mo
يَسْأَلُونَكَ عَنِ الْأَهِلَّةِ ۖ قُلْ هِيَ مَوَاقِيتُ لِلنَّاسِ وَالْحَجِّ ۗ وَلَيْسَ الْبِرُّ بِأَنْ تَأْتُوا الْبُيُوتَ مِنْ ظُهُورِهَا وَلَٰكِنَّ الْبِرَّ مَنِ اتَّقَىٰ ۗ وَأْتُوا الْبُيُوتَ مِنْ أَبْوَابِهَا ۚ وَاتَّقُوا اللَّهَ لَعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ
Won n bi o leere nipa iletesu. So pe: “Ohun ni (onka) akoko fun awon eniyan ati (onka akoko fun) ise Hajj. Ki i se ise rere (fun yin) lati gba eyin-inkule wonu ile, sugbon (oluse) rere ni eni ti o ba beru (Allahu). E gba enu-ona wonu ile. Ki e si beru Allahu nitori ki e le jere
وَقَاتِلُوا فِي سَبِيلِ اللَّهِ الَّذِينَ يُقَاتِلُونَكُمْ وَلَا تَعْتَدُوا ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ الْمُعْتَدِينَ
Fun aabo esin Allahu, e pa awon t’o n ja yin logun. Ki e si ma se tayo enu-ala. Dajudaju Allahu ko nifee awon olutayo enu-ala
وَاقْتُلُوهُمْ حَيْثُ ثَقِفْتُمُوهُمْ وَأَخْرِجُوهُمْ مِنْ حَيْثُ أَخْرَجُوكُمْ ۚ وَالْفِتْنَةُ أَشَدُّ مِنَ الْقَتْلِ ۚ وَلَا تُقَاتِلُوهُمْ عِنْدَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ حَتَّىٰ يُقَاتِلُوكُمْ فِيهِ ۖ فَإِنْ قَاتَلُوكُمْ فَاقْتُلُوهُمْ ۗ كَذَٰلِكَ جَزَاءُ الْكَافِرِينَ
E pa won nibikibi ti owo yin ba ti ba won. Ki e si le won jade kuro nibi ti won ti le yin jade. Ifooro le ju pipa lo. E ma se ba won ja ni Mosalasi Haram afi igba ti won ba ba yin ja ninu re. Nitori naa, ti won ba ba yin ja, e ba won ja. Bayen ni esan awon alaigbagbo
فَإِنِ انْتَهَوْا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَحِيمٌ
Ti won ba si jawo (ninu iborisa), dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun

Choose other languages: