Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #20 Translated in Yoruba

أُولَٰئِكَ الَّذِينَ اشْتَرَوُا الضَّلَالَةَ بِالْهُدَىٰ فَمَا رَبِحَتْ تِجَارَتُهُمْ وَمَا كَانُوا مُهْتَدِينَ
Awon wonyen ni awon t’o fi imona ra isina. Nitori naa, okowo won ko lere, won ko si je olumona
مَثَلُهُمْ كَمَثَلِ الَّذِي اسْتَوْقَدَ نَارًا فَلَمَّا أَضَاءَتْ مَا حَوْلَهُ ذَهَبَ اللَّهُ بِنُورِهِمْ وَتَرَكَهُمْ فِي ظُلُمَاتٍ لَا يُبْصِرُونَ
Apejuwe won da bi apejuwe eni ti o tan ina, sugbon nigba ti imole tan si ayika re tan, Allahu mu imole won lo, O si fi won sile sinu awon okunkun; won ko si riran mo
صُمٌّ بُكْمٌ عُمْيٌ فَهُمْ لَا يَرْجِعُونَ
Aditi, ayaya, afoju ni won; nitori naa won ko nii seri pada
أَوْ كَصَيِّبٍ مِنَ السَّمَاءِ فِيهِ ظُلُمَاتٌ وَرَعْدٌ وَبَرْقٌ يَجْعَلُونَ أَصَابِعَهُمْ فِي آذَانِهِمْ مِنَ الصَّوَاعِقِ حَذَرَ الْمَوْتِ ۚ وَاللَّهُ مُحِيطٌ بِالْكَافِرِينَ
Tabi (apejuwe won) da bi ojo nla ti n ro lati sanmo. O mu awon okunkun, ara sisan ati monamona lowo. Won n fi ika won sinu eti won nitori igbe ara sisan fun iberu iku. Allahu si yi awon alaigbagbo ka
يَكَادُ الْبَرْقُ يَخْطَفُ أَبْصَارَهُمْ ۖ كُلَّمَا أَضَاءَ لَهُمْ مَشَوْا فِيهِ وَإِذَا أَظْلَمَ عَلَيْهِمْ قَامُوا ۚ وَلَوْ شَاءَ اللَّهُ لَذَهَبَ بِسَمْعِهِمْ وَأَبْصَارِهِمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Monamona naa fee mu iriran won lo. Nigbakigba ti o ba tan imole si won, won a rin lo ninu re. Nigba ti o ba si soookun mo won, won a duro si. Ati pe ti o ba je pe Allahu ba fe, dajudaju iba gba igboro won ati iriran won. Dajudaju Allahu ni Alagbara lori gbogbo nnkan

Choose other languages: