Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #170 Translated in Yoruba

إِذْ تَبَرَّأَ الَّذِينَ اتُّبِعُوا مِنَ الَّذِينَ اتَّبَعُوا وَرَأَوُا الْعَذَابَ وَتَقَطَّعَتْ بِهِمُ الْأَسْبَابُ
(Ranti) nigba ti awon ti won tele (ninu aigbagbo) maa yowo yose kuro ninu oro awon t’o tele won; (nigba ti) won ba foju ri Iya, ti ohun t’o so won po si ja patapata
وَقَالَ الَّذِينَ اتَّبَعُوا لَوْ أَنَّ لَنَا كَرَّةً فَنَتَبَرَّأَ مِنْهُمْ كَمَا تَبَرَّءُوا مِنَّا ۗ كَذَٰلِكَ يُرِيهِمُ اللَّهُ أَعْمَالَهُمْ حَسَرَاتٍ عَلَيْهِمْ ۖ وَمَا هُمْ بِخَارِجِينَ مِنَ النَّارِ
Awon t’o tele won yo si wi pe: “Ti o ba je pe dajudaju ipadawaye le wa fun wa ni, awa iba yowo yose kuro ninu oro won ni gege bi won se yowo yose kuro ninu oro wa.” Bayen ni Allahu yo se fi awon ise won han won ni (ise) ofo fun won. Won ko si nii jade kuro ninu Ina
يَا أَيُّهَا النَّاسُ كُلُوا مِمَّا فِي الْأَرْضِ حَلَالًا طَيِّبًا وَلَا تَتَّبِعُوا خُطُوَاتِ الشَّيْطَانِ ۚ إِنَّهُ لَكُمْ عَدُوٌّ مُبِينٌ
Eyin eniyan, e je ninu ohun ti n be ninu ile (t’o je) eto (ati nnkan) daadaa.E ma si se tele awon oju-ese Esu. Dajudaju oun ni ota ponnbele fun yin
إِنَّمَا يَأْمُرُكُمْ بِالسُّوءِ وَالْفَحْشَاءِ وَأَنْ تَقُولُوا عَلَى اللَّهِ مَا لَا تَعْلَمُونَ
Ohun ti o maa pa yin ni ase re ni (ise) aburu, ibaje ati siso nipa Allahu ohun ti e o nimo re
وَإِذَا قِيلَ لَهُمُ اتَّبِعُوا مَا أَنْزَلَ اللَّهُ قَالُوا بَلْ نَتَّبِعُ مَا أَلْفَيْنَا عَلَيْهِ آبَاءَنَا ۗ أَوَلَوْ كَانَ آبَاؤُهُمْ لَا يَعْقِلُونَ شَيْئًا وَلَا يَهْتَدُونَ
Nigba ti won ba so fun won pe

Choose other languages: