Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #155 Translated in Yoruba

كَمَا أَرْسَلْنَا فِيكُمْ رَسُولًا مِنْكُمْ يَتْلُو عَلَيْكُمْ آيَاتِنَا وَيُزَكِّيكُمْ وَيُعَلِّمُكُمُ الْكِتَابَ وَالْحِكْمَةَ وَيُعَلِّمُكُمْ مَا لَمْ تَكُونُوا تَعْلَمُونَ
gege bi A se ran Ojise kan si yin laaarin ara yin, ti o n ke awon ayah Wa fun yin, ti o n so yin di eni mimo, ti o n ko yin ni Tira ati ogbon ijinle (sunnah), ti o si n ko yin ni ohun ti e o mo tele
فَاذْكُرُونِي أَذْكُرْكُمْ وَاشْكُرُوا لِي وَلَا تَكْفُرُونِ
Nitori naa, e ranti Mi, Mo maa ranti yin. E dupe fun Mi, e ma sai moore si Mi
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اسْتَعِينُوا بِالصَّبْرِ وَالصَّلَاةِ ۚ إِنَّ اللَّهَ مَعَ الصَّابِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e fi suuru ati irun kiki toro oore (Allahu). Dajudaju Allahu n be pelu awon onisuuru
وَلَا تَقُولُوا لِمَنْ يُقْتَلُ فِي سَبِيلِ اللَّهِ أَمْوَاتٌ ۚ بَلْ أَحْيَاءٌ وَلَٰكِنْ لَا تَشْعُرُونَ
E ma se pe awon ti won n pa si oju-ogun esin Allahu ni oku (iya), amo alaaye (eni ike) ni won, sugbon eyin ko fura
وَلَنَبْلُوَنَّكُمْ بِشَيْءٍ مِنَ الْخَوْفِ وَالْجُوعِ وَنَقْصٍ مِنَ الْأَمْوَالِ وَالْأَنْفُسِ وَالثَّمَرَاتِ ۗ وَبَشِّرِ الصَّابِرِينَ
Dajudaju A o maa dan yin wo pelu kini kan latara eru, ebi, adinku ninu awon dukia, awon emi ati awon eso. Ki o si fun awon onisuuru ni iro idunnu

Choose other languages: