Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #153 Translated in Yoruba

وَمِنْ حَيْثُ خَرَجْتَ فَوَلِّ وَجْهَكَ شَطْرَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ ۖ وَإِنَّهُ لَلْحَقُّ مِنْ رَبِّكَ ۗ وَمَا اللَّهُ بِغَافِلٍ عَمَّا تَعْمَلُونَ
Ibikibi ti o ba jade lo, koju re si agbegbe Mosalasi Haram, nitori pe dajudaju ododo ni lati odo Oluwa re. Allahu ko si nii gbagbe ohun ti e n se nise
وَمِنْ حَيْثُ خَرَجْتَ فَوَلِّ وَجْهَكَ شَطْرَ الْمَسْجِدِ الْحَرَامِ ۚ وَحَيْثُ مَا كُنْتُمْ فَوَلُّوا وُجُوهَكُمْ شَطْرَهُ لِئَلَّا يَكُونَ لِلنَّاسِ عَلَيْكُمْ حُجَّةٌ إِلَّا الَّذِينَ ظَلَمُوا مِنْهُمْ فَلَا تَخْشَوْهُمْ وَاخْشَوْنِي وَلِأُتِمَّ نِعْمَتِي عَلَيْكُمْ وَلَعَلَّكُمْ تَهْتَدُونَ
Ibikibi ti o ba jade lo, koju re si agbegbe Mosalasi Haram. Ati pe ibikibi ti e ba wa, e koju yin si agbegbe re, nitori ki awon eniyan ma baa ni awijare lori yin, ayafi awon ti won sabosi ninu won (ti won ko ye ja yin niyan). Nitori naa, e ma se paya won. E paya Mi, nitori ki Ng le pe idera Mi fun yin ati nitori ki e le mona ooji re maa wa ni egbe otun re nikete ti oorun ba yetari. Nigba ti opin eba oke ila oorun n je ariwa-ila oorun (north-east) opin eba isale ila oorun si n je gusu-ila oorun (south-east). Nitori naa
كَمَا أَرْسَلْنَا فِيكُمْ رَسُولًا مِنْكُمْ يَتْلُو عَلَيْكُمْ آيَاتِنَا وَيُزَكِّيكُمْ وَيُعَلِّمُكُمُ الْكِتَابَ وَالْحِكْمَةَ وَيُعَلِّمُكُمْ مَا لَمْ تَكُونُوا تَعْلَمُونَ
gege bi A se ran Ojise kan si yin laaarin ara yin, ti o n ke awon ayah Wa fun yin, ti o n so yin di eni mimo, ti o n ko yin ni Tira ati ogbon ijinle (sunnah), ti o si n ko yin ni ohun ti e o mo tele
فَاذْكُرُونِي أَذْكُرْكُمْ وَاشْكُرُوا لِي وَلَا تَكْفُرُونِ
Nitori naa, e ranti Mi, Mo maa ranti yin. E dupe fun Mi, e ma sai moore si Mi
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اسْتَعِينُوا بِالصَّبْرِ وَالصَّلَاةِ ۚ إِنَّ اللَّهَ مَعَ الصَّابِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e fi suuru ati irun kiki toro oore (Allahu). Dajudaju Allahu n be pelu awon onisuuru

Choose other languages: