Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #30 Translated in Yoruba

فَرَاغَ إِلَىٰ أَهْلِهِ فَجَاءَ بِعِجْلٍ سَمِينٍ
O lo si odo awon ara ile re, o si de pelu omo maalu oloraa (ayangbe)
فَقَرَّبَهُ إِلَيْهِمْ قَالَ أَلَا تَأْكُلُونَ
O gbe e sunmo odo won. O si so pe: "Se e o nii jeun ni
فَأَوْجَسَ مِنْهُمْ خِيفَةً ۖ قَالُوا لَا تَخَفْ ۖ وَبَشَّرُوهُ بِغُلَامٍ عَلِيمٍ
Nigba naa, o ni ipaya won ninu okan. Won so pe: "Ma se paya." Won si fun un ni iro idunnu nipa bibi omokunrin onimo kan
فَأَقْبَلَتِ امْرَأَتُهُ فِي صَرَّةٍ فَصَكَّتْ وَجْهَهَا وَقَالَتْ عَجُوزٌ عَقِيمٌ
Nigba naa, iyawo re si bere igbe, o si gbara re loju, o so pe: "Arugbo, agan (ma ni mi)
قَالُوا كَذَٰلِكِ قَالَ رَبُّكِ ۖ إِنَّهُ هُوَ الْحَكِيمُ الْعَلِيمُ
Won so pe: "Bayen ni Oluwa re so. Dajudaju Oun ni Ologbon, Onimo

Choose other languages: