Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #33 Translated in Yoruba

فَأَقْبَلَتِ امْرَأَتُهُ فِي صَرَّةٍ فَصَكَّتْ وَجْهَهَا وَقَالَتْ عَجُوزٌ عَقِيمٌ
Nigba naa, iyawo re si bere igbe, o si gbara re loju, o so pe: "Arugbo, agan (ma ni mi)
قَالُوا كَذَٰلِكِ قَالَ رَبُّكِ ۖ إِنَّهُ هُوَ الْحَكِيمُ الْعَلِيمُ
Won so pe: "Bayen ni Oluwa re so. Dajudaju Oun ni Ologbon, Onimo
قَالَ فَمَا خَطْبُكُمْ أَيُّهَا الْمُرْسَلُونَ
(Anabi ’Ibrohim) so pe: "Ki tun ni oro ti e ba wa, eyin Ojise
قَالُوا إِنَّا أُرْسِلْنَا إِلَىٰ قَوْمٍ مُجْرِمِينَ
Won so pe: "Dajudaju Won ran wa nise si ijo elese ni
لِنُرْسِلَ عَلَيْهِمْ حِجَارَةً مِنْ طِينٍ
nitori ki a le fi okuta amo (sisun) ranse si won

Choose other languages: