Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #178 Translated in Yoruba

فَانْقَلَبُوا بِنِعْمَةٍ مِنَ اللَّهِ وَفَضْلٍ لَمْ يَمْسَسْهُمْ سُوءٌ وَاتَّبَعُوا رِضْوَانَ اللَّهِ ۗ وَاللَّهُ ذُو فَضْلٍ عَظِيمٍ
Nitori naa, won pada dele pelu ike ati oore-ajulo lati odo Allahu. Aburu kan ko si kan won. Ati pe won (sise) to iyonu Allahu. Allahu si ni Oloore nla
إِنَّمَا ذَٰلِكُمُ الشَّيْطَانُ يُخَوِّفُ أَوْلِيَاءَهُ فَلَا تَخَافُوهُمْ وَخَافُونِ إِنْ كُنْتُمْ مُؤْمِنِينَ
Dajudaju iyen ni Esu, ti n fi awon ore re deru ba yin. Nitori naa, e ma se beru won. Ki e si beru Mi ti e ba je onigbagbo ododo
وَلَا يَحْزُنْكَ الَّذِينَ يُسَارِعُونَ فِي الْكُفْرِ ۚ إِنَّهُمْ لَنْ يَضُرُّوا اللَّهَ شَيْئًا ۗ يُرِيدُ اللَّهُ أَلَّا يَجْعَلَ لَهُمْ حَظًّا فِي الْآخِرَةِ ۖ وَلَهُمْ عَذَابٌ عَظِيمٌ
Ma se je ki awon ti n sare ko sinu aigbagbo ko ibanuje ba o. Dajudaju won ko le ko inira kan ba Allahu. Allahu ko fe ki ipin kan ninu oore wa fun won ni orun (ni); iya nla si n be fun won
إِنَّ الَّذِينَ اشْتَرَوُا الْكُفْرَ بِالْإِيمَانِ لَنْ يَضُرُّوا اللَّهَ شَيْئًا وَلَهُمْ عَذَابٌ أَلِيمٌ
Dajudaju awon t’o fi igbagbo ododo ra aigbagbo, won ko le ko inira kan ba Allahu. Iya eleta-elero si wa fun won
وَلَا يَحْسَبَنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا أَنَّمَا نُمْلِي لَهُمْ خَيْرٌ لِأَنْفُسِهِمْ ۚ إِنَّمَا نُمْلِي لَهُمْ لِيَزْدَادُوا إِثْمًا ۚ وَلَهُمْ عَذَابٌ مُهِينٌ
Ki awon t’o sai gbagbo ma se lero pe bi A se n lora fun won je oore fun won. A kan n lora fun won nitori ki won le lekun ninu ese ni. Iya ti i yepere eda si wa fun won

Choose other languages: