Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #125 Translated in Yoruba

وَإِذْ غَدَوْتَ مِنْ أَهْلِكَ تُبَوِّئُ الْمُؤْمِنِينَ مَقَاعِدَ لِلْقِتَالِ ۗ وَاللَّهُ سَمِيعٌ عَلِيمٌ
(Ranti) nigba ti o ji kuro lodo awon ara ile re ni idaji kutukutu, ti o si n fi aye ibujagun han awon onigbagbo ododo, Allahu ni Olugbo, Onimo
إِذْ هَمَّتْ طَائِفَتَانِ مِنْكُمْ أَنْ تَفْشَلَا وَاللَّهُ وَلِيُّهُمَا ۗ وَعَلَى اللَّهِ فَلْيَتَوَكَّلِ الْمُؤْمِنُونَ
(Ranti) nigba ti ijo meji ninu yin fe sojo. Allahu si ni Alafeyinti awon mejeeji. Allahu si ni ki awon onigbagbo ododo gbarale
وَلَقَدْ نَصَرَكُمُ اللَّهُ بِبَدْرٍ وَأَنْتُمْ أَذِلَّةٌ ۖ فَاتَّقُوا اللَّهَ لَعَلَّكُمْ تَشْكُرُونَ
Allahu kuku fun yin ni isegun ni ogun Badr, nigba ti eyin je alailagbara. Nitori naa, e beru Allahu ki e le dupe (fun Un)
إِذْ تَقُولُ لِلْمُؤْمِنِينَ أَلَنْ يَكْفِيَكُمْ أَنْ يُمِدَّكُمْ رَبُّكُمْ بِثَلَاثَةِ آلَافٍ مِنَ الْمَلَائِكَةِ مُنْزَلِينَ
Ranti nigba ti o n so fun awon onigbagbo ododo pe: “Se ko nii to yin ti Oluwa yin ba se iranlowo fun yin pelu egberun meta ninu awon molaika, ti Won maa sokale?”
بَلَىٰ ۚ إِنْ تَصْبِرُوا وَتَتَّقُوا وَيَأْتُوكُمْ مِنْ فَوْرِهِمْ هَٰذَا يُمْدِدْكُمْ رَبُّكُمْ بِخَمْسَةِ آلَافٍ مِنَ الْمَلَائِكَةِ مُسَوِّمِينَ
Rara (o maa to wa.). Ti eyin ba se suuru, ti e si beru Allahu, ti awon (ota) ba de ba yin lojiji, Oluwa yin yoo ran yin lowo pelu egberun maarun ninu awon molaika pelu ami idanimo lara won

Choose other languages: