Quran Apps in many lanuages:

Surah Ash-Shura Ayahs #52 Translated in Yoruba

فَإِنْ أَعْرَضُوا فَمَا أَرْسَلْنَاكَ عَلَيْهِمْ حَفِيظًا ۖ إِنْ عَلَيْكَ إِلَّا الْبَلَاغُ ۗ وَإِنَّا إِذَا أَذَقْنَا الْإِنْسَانَ مِنَّا رَحْمَةً فَرِحَ بِهَا ۖ وَإِنْ تُصِبْهُمْ سَيِّئَةٌ بِمَا قَدَّمَتْ أَيْدِيهِمْ فَإِنَّ الْإِنْسَانَ كَفُورٌ
Nitori naa, ti won ba gbunri, A o ran o pe ki o je oluso fun won. Ko si kini kan t’o di dandan fun o bi ko se ise-jije. Ati pe dajudaju nigba ti A ba fun eniyan ni ike kan to wo lati odo Wa, o maa dunnu si i. Ti aburu kan ba si kan an nipase ohun ti owo won ti siwaju (ni ise aburu), dajudaju eniyan ni alaimoore
لِلَّهِ مُلْكُ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ يَخْلُقُ مَا يَشَاءُ ۚ يَهَبُ لِمَنْ يَشَاءُ إِنَاثًا وَيَهَبُ لِمَنْ يَشَاءُ الذُّكُورَ
Ti Allahu ni ijoba awon sanmo ati ile. O n seda ohun ti O ba fe. O n ta eni ti O ba fe lore omobinrin. O si n ta eni ti O ba fe ni lore omokunrin
أَوْ يُزَوِّجُهُمْ ذُكْرَانًا وَإِنَاثًا ۖ وَيَجْعَلُ مَنْ يَشَاءُ عَقِيمًا ۚ إِنَّهُ عَلِيمٌ قَدِيرٌ
Tabi ki O se won ni orisi meji; omokunrin ati omobinrin. O si n se eni ti O ba fe ni agan. Dajudaju Oun ni Onimo, Alagbara
وَمَا كَانَ لِبَشَرٍ أَنْ يُكَلِّمَهُ اللَّهُ إِلَّا وَحْيًا أَوْ مِنْ وَرَاءِ حِجَابٍ أَوْ يُرْسِلَ رَسُولًا فَيُوحِيَ بِإِذْنِهِ مَا يَشَاءُ ۚ إِنَّهُ عَلِيٌّ حَكِيمٌ
Ko letoo fun abara kan pe ki Allahu ba a soro afi ki (oro naa) je imisi (isipaya mimo), tabi ki o je leyin gaga, tabi ki O ran Ojise kan (ti)
وَكَذَٰلِكَ أَوْحَيْنَا إِلَيْكَ رُوحًا مِنْ أَمْرِنَا ۚ مَا كُنْتَ تَدْرِي مَا الْكِتَابُ وَلَا الْإِيمَانُ وَلَٰكِنْ جَعَلْنَاهُ نُورًا نَهْدِي بِهِ مَنْ نَشَاءُ مِنْ عِبَادِنَا ۚ وَإِنَّكَ لَتَهْدِي إِلَىٰ صِرَاطٍ مُسْتَقِيمٍ
Bayen si ni A se fi imisi ranse si o ninu ase Wa. Iwo ko mo ki ni Tira ati igbagbo ododo tele (siwaju imisi naa),1 sugbon A se imisi naa ni imole kan ti A n fi se imona fun eni ti A ba fe ninu awon erusin Wa. Dajudaju iwo n pepe si ona taara (’Islam). 2 ise wiridi ni Anabi (sollalahu alayhi wa sallam) maa n se ninu ogbun Hira siwaju ki o to di Anabi Olohun iro l’o fi pa. Idi ni pe

Choose other languages: