Quran Apps in many lanuages:

Surah Ash-Shams Ayahs #13 Translated in Yoruba

قَدْ أَفْلَحَ مَنْ زَكَّاهَا
Enikeni ti o ba safomo (emi ara) re (nibi ese), o ma ti jere
وَقَدْ خَابَ مَنْ دَسَّاهَا
Enikeni ti o ba fi (iwa ese) ba emi (ara) re je, o ma ti padanu
كَذَّبَتْ ثَمُودُ بِطَغْوَاهَا
Ijo Thamud pe ododo niro nipa itayo enu-ala won
إِذِ انْبَعَثَ أَشْقَاهَا
(Ranti) nigba ti eni ti ori re buru julo ninu won sare dide (lati gun rakunmi pa)
فَقَالَ لَهُمْ رَسُولُ اللَّهِ نَاقَةَ اللَّهِ وَسُقْيَاهَا
Nigba naa, Ojise Allahu so fun won pe: "(E fi) abo rakunmi Allahu ati omi re (sile)

Choose other languages: