Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #53 Translated in Yoruba

أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ يُزَكُّونَ أَنْفُسَهُمْ ۚ بَلِ اللَّهُ يُزَكِّي مَنْ يَشَاءُ وَلَا يُظْلَمُونَ فَتِيلًا
Se o o ri awon t’o n safomo ara won ni? Ko si ri bee, Allahu l’O n safomo eni ti O ba fe. Ko si nii sabosi bin-intin si won
انْظُرْ كَيْفَ يَفْتَرُونَ عَلَى اللَّهِ الْكَذِبَ ۖ وَكَفَىٰ بِهِ إِثْمًا مُبِينًا
Wo bi won se n da adapa iro mo Allahu. O si to ni ese ponnbele
أَلَمْ تَرَ إِلَى الَّذِينَ أُوتُوا نَصِيبًا مِنَ الْكِتَابِ يُؤْمِنُونَ بِالْجِبْتِ وَالطَّاغُوتِ وَيَقُولُونَ لِلَّذِينَ كَفَرُوا هَٰؤُلَاءِ أَهْدَىٰ مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا سَبِيلًا
Se o o ri awon ti A fun ni ipin kan ninu tira, ti won n gbagbo ninu idan ati orisa, won si n wi fun awon alaigbagbo pe: “Awon (osebo) wonyi mona ju awon t’o gbagbo lododo.”
أُولَٰئِكَ الَّذِينَ لَعَنَهُمُ اللَّهُ ۖ وَمَنْ يَلْعَنِ اللَّهُ فَلَنْ تَجِدَ لَهُ نَصِيرًا
Awon wonyen ni awon ti Allahu sebi le. Enikeni ti Allahu ba si sebi le, o o nii ri alaranse kan fun un
أَمْ لَهُمْ نَصِيبٌ مِنَ الْمُلْكِ فَإِذًا لَا يُؤْتُونَ النَّاسَ نَقِيرًا
Tabi ipin kan n be fun won ninu ijoba (Wa) ni? Ti o ba ri bee won ko nii fun awon eniyan ni eekan koro dabinu

Choose other languages: