Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nahl Ayahs #21 Translated in Yoruba

أَفَمَنْ يَخْلُقُ كَمَنْ لَا يَخْلُقُ ۗ أَفَلَا تَذَكَّرُونَ
Nje Eni ti O da eda da bi eni ti ko da eda bi? Nitori naa, se e o nii lo iranti ni
وَإِنْ تَعُدُّوا نِعْمَةَ اللَّهِ لَا تُحْصُوهَا ۗ إِنَّ اللَّهَ لَغَفُورٌ رَحِيمٌ
Ti e ba sonka idera Allahu, e ko le ka a tan. Dajudaju Allahu ma ni Alaforijin, Onikee
وَاللَّهُ يَعْلَمُ مَا تُسِرُّونَ وَمَا تُعْلِنُونَ
Ati pe Allahu mo ohun ti e n fi pamo ati ohun ti e n se afihan re
وَالَّذِينَ يَدْعُونَ مِنْ دُونِ اللَّهِ لَا يَخْلُقُونَ شَيْئًا وَهُمْ يُخْلَقُونَ
Awon (orisa) ti won n pe leyin Allahu; won ko le da kini kan. Allahu l’O si seda won
أَمْوَاتٌ غَيْرُ أَحْيَاءٍ ۖ وَمَا يَشْعُرُونَ أَيَّانَ يُبْعَثُونَ
Oku (ni won), won ki i se alaaye. Won ko si mo akoko ti A oo gbe won dide. won ki i se alaaye.” ko so iku Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) di ohun t’o ti sele. Sebi awon molaika kan wa lara nnkan ti awon eniyan n josin fun leyin Allahu. Se oku ni awon molaika naa ni tabi alaaye? A o kuku ti i gbo iku molaika kan kan ri. Bakan naa as-Saton ar-Rojim je okan pataki ninu ohun ti awon eniyan n josin fun. Se oku ni Saeton naa ni tabi alaaye? Rara bi Allahu se fe.” Ko wa si eri taara kan kan t’o fi rinle pe Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ti ku bi ko se ayah oniponna eyi ti a ti se alaye lori re siwaju ninu itose-oro fun surah ali-’Imron 3:55. Dipo ki a ri ayah kan tabi hadith kan taara lori iku Anabi ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) hadith t’o n fi ipadabo re rinle l’a n ri. Eni ti ko i ku l’o si le pada wa sile aye. ” ninu ayah naa ki i se itumo adamo. Idi ni pe ere ti ko si emi lara re ni awon orisa naa. Ipo oku eni ti ko le soro

Choose other languages: