Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Mursalat Ayahs #6 Translated in Yoruba

فَالْعَاصِفَاتِ عَصْفًا
O bura pelu awon iji ategun t’o n ja
وَالنَّاشِرَاتِ نَشْرًا
O bura pelu awon ategun t’o n tu esujo ka
فَالْفَارِقَاتِ فَرْقًا
O bura pelu awon t’o n sepinya laaarin ododo ati iro
فَالْمُلْقِيَاتِ ذِكْرًا
O tun bura pelu awon molaika t’o n mu iranti wa (ba awon Ojise)
عُذْرًا أَوْ نُذْرًا
(Iranti naa je) awijare tabi ikilo

Choose other languages: