Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Mursalat Ayahs #9 Translated in Yoruba

فَالْمُلْقِيَاتِ ذِكْرًا
O tun bura pelu awon molaika t’o n mu iranti wa (ba awon Ojise)
عُذْرًا أَوْ نُذْرًا
(Iranti naa je) awijare tabi ikilo
إِنَّمَا تُوعَدُونَ لَوَاقِعٌ
Dajudaju ohun ti A se ni adehun fun yin kuku maa sele
فَإِذَا النُّجُومُ طُمِسَتْ
Nitori naa, nigba ti won ba pa (imole) irawo re
وَإِذَا السَّمَاءُ فُرِجَتْ
ati nigba ti won ba si sanmo sile gbagada

Choose other languages: