Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Lail Ayahs #12 Translated in Yoruba

وَأَمَّا مَنْ بَخِلَ وَاسْتَغْنَىٰ
Ni ti eni ti o ba yahun, ti o si ri ara re leni t’o roro tayo esan orun
وَكَذَّبَ بِالْحُسْنَىٰ
(ti) o tun pe esan rere ni iro
فَسَنُيَسِّرُهُ لِلْعُسْرَىٰ
A si maa se ise aburu ni irorun fun un
وَمَا يُغْنِي عَنْهُ مَالُهُ إِذَا تَرَدَّىٰ
Dukia re ko si nii ro o loro nigba ti o ba ja bo (sinu Ina)
إِنَّ عَلَيْنَا لَلْهُدَىٰ
Dajudaju tiWa ni (lati salaye) imona

Choose other languages: