Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Lail Ayahs #13 Translated in Yoruba

وَكَذَّبَ بِالْحُسْنَىٰ
(ti) o tun pe esan rere ni iro
فَسَنُيَسِّرُهُ لِلْعُسْرَىٰ
A si maa se ise aburu ni irorun fun un
وَمَا يُغْنِي عَنْهُ مَالُهُ إِذَا تَرَدَّىٰ
Dukia re ko si nii ro o loro nigba ti o ba ja bo (sinu Ina)
إِنَّ عَلَيْنَا لَلْهُدَىٰ
Dajudaju tiWa ni (lati salaye) imona
وَإِنَّ لَنَا لَلْآخِرَةَ وَالْأُولَىٰ
Ati pe dajudaju tiWa ni orun ati aye

Choose other languages: