Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #123 Translated in Yoruba

إِنَّا أَرْسَلْنَاكَ بِالْحَقِّ بَشِيرًا وَنَذِيرًا ۖ وَلَا تُسْأَلُ عَنْ أَصْحَابِ الْجَحِيمِ
Dajudaju Awa fi ododo ran o nise. (O si je) oniroo-idunnu ati olukilo (fun gbogbo aye). Won ko si nii bi o leere nipa awon ero inu Ina
وَلَنْ تَرْضَىٰ عَنْكَ الْيَهُودُ وَلَا النَّصَارَىٰ حَتَّىٰ تَتَّبِعَ مِلَّتَهُمْ ۗ قُلْ إِنَّ هُدَى اللَّهِ هُوَ الْهُدَىٰ ۗ وَلَئِنِ اتَّبَعْتَ أَهْوَاءَهُمْ بَعْدَ الَّذِي جَاءَكَ مِنَ الْعِلْمِ ۙ مَا لَكَ مِنَ اللَّهِ مِنْ وَلِيٍّ وَلَا نَصِيرٍ
Awon yehudi ati nasara ko nii yonu si o titi o fi maa tele esin won. So pe: “Dajudaju imona ti Allahu ni imona.” Dajudaju ti o ba si tele ife-inu won leyin eyi ti o de ba o ninu imo (’Islam), ko nii si alaabo ati alaranse kan fun o lodo Allahu
الَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ يَتْلُونَهُ حَقَّ تِلَاوَتِهِ أُولَٰئِكَ يُؤْمِنُونَ بِهِ ۗ وَمَنْ يَكْفُرْ بِهِ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الْخَاسِرُونَ
Awon ti A fun ni Tira (al-Ƙur’an), won n ke e ni kike eto. Awon wonyen gba a gbo ni ododo. Awon t’o sai gbagbo ninu re, awon wonyen ni eni ofo
يَا بَنِي إِسْرَائِيلَ اذْكُرُوا نِعْمَتِيَ الَّتِي أَنْعَمْتُ عَلَيْكُمْ وَأَنِّي فَضَّلْتُكُمْ عَلَى الْعَالَمِينَ
Eyin omo ’Isro’il, e ranti ike Mi, eyi ti Mo se fun yin. Dajudaju Emi tun soore ajulo fun yin lori awon
وَاتَّقُوا يَوْمًا لَا تَجْزِي نَفْسٌ عَنْ نَفْسٍ شَيْئًا وَلَا يُقْبَلُ مِنْهَا عَدْلٌ وَلَا تَنْفَعُهَا شَفَاعَةٌ وَلَا هُمْ يُنْصَرُونَ
E beru ojo kan ti emi kan ko nii sanfaani kini kan fun emi kan. A o si nii gba aaro lowo re. Isipe kan ko nii wulo fun un. A o si nii ran won lowo

Choose other languages: