Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #15 Translated in Yoruba

وَإِذَا قِيلَ لَهُمْ لَا تُفْسِدُوا فِي الْأَرْضِ قَالُوا إِنَّمَا نَحْنُ مُصْلِحُونَ
Nigba ti won ba so fun won pe: “E ma sebaje lori ile.” Won a wi pe: “Awa ni alatun-unse.”
أَلَا إِنَّهُمْ هُمُ الْمُفْسِدُونَ وَلَٰكِنْ لَا يَشْعُرُونَ
E kiye si i! Dajudaju awon gan-an ni obileje, sugbon won ko fura
وَإِذَا قِيلَ لَهُمْ آمِنُوا كَمَا آمَنَ النَّاسُ قَالُوا أَنُؤْمِنُ كَمَا آمَنَ السُّفَهَاءُ ۗ أَلَا إِنَّهُمْ هُمُ السُّفَهَاءُ وَلَٰكِنْ لَا يَعْلَمُونَ
Nigba ti won ba so fun won pe: “E gbagbo ni ododo gege bi awon eniyan se gbagbo.” Won a wi pe: “Se ki a gbagbo gege bi awon omugo se gbagbo ni?” E kiye si i! Dajudaju awon gan-an ni omugo, sugbon won ko mo
وَإِذَا لَقُوا الَّذِينَ آمَنُوا قَالُوا آمَنَّا وَإِذَا خَلَوْا إِلَىٰ شَيَاطِينِهِمْ قَالُوا إِنَّا مَعَكُمْ إِنَّمَا نَحْنُ مُسْتَهْزِئُونَ
Nigba ti won ba pade awon t’o gbagbo ni ododo, won a wi pe: “A gbagbo.” Nigba ti o ba si ku won ku awon (eni) esu won, won a wi pe: “Dajudaju awa n be pelu yin, awa kan n se yeye ni.”
اللَّهُ يَسْتَهْزِئُ بِهِمْ وَيَمُدُّهُمْ فِي طُغْيَانِهِمْ يَعْمَهُونَ
Allahu maa fi won se yeye. O si maa mu won lekun si i ninu agbere won, ti won yoo maa pa ridarida. ti awon ise naa je ise t’o duro sori fifi oruko ise eda so oruko esan ise naa. Iru re l’o sele ninu ayah ti a n tose re lowo yii. Allahu (subhanahu wa ta’ala) ki i se oluseyeye (eni ti o maa n se yeye) tabi oniyeye (eni ti eda le fi se yeye). Eni kan ko si nii maa se yeye afi ki o je alawada oniranu. Allahu (subhanahu wa ta’ala) ki i se awada Allahu ki i se eletan. Eni kan ko nii je eletan afi ki o je opuro oluyapa-adehun. Allahu ki i se opuro. Allahu gan-an ni Ododo. Bakan naa

Choose other languages: