Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Anaam Ayahs #89 Translated in Yoruba

وَزَكَرِيَّا وَيَحْيَىٰ وَعِيسَىٰ وَإِلْيَاسَ ۖ كُلٌّ مِنَ الصَّالِحِينَ
Ati (Anabi) Zakariyya, Yahya, ‘Isa ati ’Ilyas; gbogbo won wa ninu awon eni rere
وَإِسْمَاعِيلَ وَالْيَسَعَ وَيُونُسَ وَلُوطًا ۚ وَكُلًّا فَضَّلْنَا عَلَى الْعَالَمِينَ
Ati ’Ismo‘il, al-Yasa‘, Yunus ati Lut; ikookan won ni A soore ajulo fun lori awon eda (asiko won)
وَمِنْ آبَائِهِمْ وَذُرِّيَّاتِهِمْ وَإِخْوَانِهِمْ ۖ وَاجْتَبَيْنَاهُمْ وَهَدَيْنَاهُمْ إِلَىٰ صِرَاطٍ مُسْتَقِيمٍ
Ati pe ninu awon baba won, aromodomo won ati awon arakunrin won, A sa won lesa. A si fi won mona taara (’Islam)
ذَٰلِكَ هُدَى اللَّهِ يَهْدِي بِهِ مَنْ يَشَاءُ مِنْ عِبَادِهِ ۚ وَلَوْ أَشْرَكُوا لَحَبِطَ عَنْهُمْ مَا كَانُوا يَعْمَلُونَ
Iyen ni imona Allahu. O si n fi to eni ti O ba fe si ona ninu awon eru Re. Ti won ba fi le sebo ni, dajudaju ohun ti won n se nise (rere) iba baje mo won lowo
أُولَٰئِكَ الَّذِينَ آتَيْنَاهُمُ الْكِتَابَ وَالْحُكْمَ وَالنُّبُوَّةَ ۚ فَإِنْ يَكْفُرْ بِهَا هَٰؤُلَاءِ فَقَدْ وَكَّلْنَا بِهَا قَوْمًا لَيْسُوا بِهَا بِكَافِرِينَ
Awon wonyen ni awon ti A fun ni Tira, ijinle oye (iyen, sunnah) ati (ipo) Anabi. Nitori naa, ti awon wonyi ba sai gbagbo ninu re, dajudaju A ti gbe e le awon eniyan kan lowo, ti won ko nii sai gbagbo ninu re

Choose other languages: