Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Anaam Ayahs #18 Translated in Yoruba

قُلْ أَغَيْرَ اللَّهِ أَتَّخِذُ وَلِيًّا فَاطِرِ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ وَهُوَ يُطْعِمُ وَلَا يُطْعَمُ ۗ قُلْ إِنِّي أُمِرْتُ أَنْ أَكُونَ أَوَّلَ مَنْ أَسْلَمَ ۖ وَلَا تَكُونَنَّ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
So pe: “Se ki ng mu oluranlowo kan yato si Allahu, Eledaa awon sanmo ati ile? Oun si ni O n bo (eda), won ki i bo O.” So pe: “Dajudaju Won pa mi lase pe ki ng je eni akoko ti o maa se ’Islam (ni asiko temi).” Iwo ko si gbodo wa ninu awon osebo. ofin Re ati ilana Re. Eyi ni awon kan mo si “sise ife-Olohun”. Ewo ninu awon Anabi Olohun ati Ojise Re ni ko juwo-juse sile patapata fun ase Allahu ofin Re ati ilana Re? Ewo ninu won se ni ko se ife-Olohun? Ko si. Idi niyi ti gbogbo won fi je musulumi gege bi Allahu (subhanahu wa ta’ala) se fi rinle ninu surah al-Baƙorah; 2:128-141. ofin Re ati ilana Re. Amo ninu ijo re oun ni eni akoko ti o koko se bee
قُلْ إِنِّي أَخَافُ إِنْ عَصَيْتُ رَبِّي عَذَابَ يَوْمٍ عَظِيمٍ
So pe: “Dajudaju emi n paya iya Ojo Nla, ti mo ba fi le yapa Oluwa mi.”
مَنْ يُصْرَفْ عَنْهُ يَوْمَئِذٍ فَقَدْ رَحِمَهُ ۚ وَذَٰلِكَ الْفَوْزُ الْمُبِينُ
Enikeni ti A ba dari re kuro nibi (iya) ni Ojo yen, (Allahu) ti saanu re. Iyen si ni erenje ponnbele
وَإِنْ يَمْسَسْكَ اللَّهُ بِضُرٍّ فَلَا كَاشِفَ لَهُ إِلَّا هُوَ ۖ وَإِنْ يَمْسَسْكَ بِخَيْرٍ فَهُوَ عَلَىٰ كُلِّ شَيْءٍ قَدِيرٌ
Ti Allahu ba fi inira kan kan o, ko si eni ti o le mu un kuro afi Oun naa. Ti O ba si mu oore kan ba o, Oun si ni Alagbara lori gbogbo nnkan
وَهُوَ الْقَاهِرُ فَوْقَ عِبَادِهِ ۚ وَهُوَ الْحَكِيمُ الْخَبِيرُ
Oun si ni Olubori t’O wa loke awon eru Re. Oun ni Ologbon, Onimo-ikoko

Choose other languages: