Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #8 Translated in Yoruba

فَالْمُقَسِّمَاتِ أَمْرًا
(O bura pelu) awon molaika t’o n pin nnkan (ti O ti pin fun eda)
إِنَّمَا تُوعَدُونَ لَصَادِقٌ
Ododo ma ni ohun ti A n se ni adehun fun yin
وَإِنَّ الدِّينَ لَوَاقِعٌ
Ati pe dajudaju Ojo Esan maa sele
وَالسَّمَاءِ ذَاتِ الْحُبُكِ
(Allahu tun bura pelu) sanmo olosoo
إِنَّكُمْ لَفِي قَوْلٍ مُخْتَلِفٍ
Dajudaju eyin wa lori oro t’o n takora won (nipa al-Ƙur’an)

Choose other languages: