Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #9 Translated in Yoruba

إِنَّمَا تُوعَدُونَ لَصَادِقٌ
Ododo ma ni ohun ti A n se ni adehun fun yin
وَإِنَّ الدِّينَ لَوَاقِعٌ
Ati pe dajudaju Ojo Esan maa sele
وَالسَّمَاءِ ذَاتِ الْحُبُكِ
(Allahu tun bura pelu) sanmo olosoo
إِنَّكُمْ لَفِي قَوْلٍ مُخْتَلِفٍ
Dajudaju eyin wa lori oro t’o n takora won (nipa al-Ƙur’an)
يُؤْفَكُ عَنْهُ مَنْ أُفِكَ
Eni ti won n se lori kuro nibi al-Ƙur’an ni eni ti Won ti se lori kuro nibe (lati inu Laohul-Mahfuth)

Choose other languages: