Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #37 Translated in Yoruba

لِنُرْسِلَ عَلَيْهِمْ حِجَارَةً مِنْ طِينٍ
nitori ki a le fi okuta amo (sisun) ranse si won
مُسَوَّمَةً عِنْدَ رَبِّكَ لِلْمُسْرِفِينَ
Won ti fami si i lara lodo Oluwa re fun awon alakoyo
فَأَخْرَجْنَا مَنْ كَانَ فِيهَا مِنَ الْمُؤْمِنِينَ
Nitori naa, A mu awon t’o je onigbagbo ododo jade kuro ninu (ilu naa)
فَمَا وَجَدْنَا فِيهَا غَيْرَ بَيْتٍ مِنَ الْمُسْلِمِينَ
A o si ri ninu (ilu naa) tayo ile kan t’o je ti awon musulumi
وَتَرَكْنَا فِيهَا آيَةً لِلَّذِينَ يَخَافُونَ الْعَذَابَ الْأَلِيمَ
A si fi ami kan sile ninu (ilu naa) fun awon t’o n paya iya eleta-elero

Choose other languages: