Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #39 Translated in Yoruba

فَأَخْرَجْنَا مَنْ كَانَ فِيهَا مِنَ الْمُؤْمِنِينَ
Nitori naa, A mu awon t’o je onigbagbo ododo jade kuro ninu (ilu naa)
فَمَا وَجَدْنَا فِيهَا غَيْرَ بَيْتٍ مِنَ الْمُسْلِمِينَ
A o si ri ninu (ilu naa) tayo ile kan t’o je ti awon musulumi
وَتَرَكْنَا فِيهَا آيَةً لِلَّذِينَ يَخَافُونَ الْعَذَابَ الْأَلِيمَ
A si fi ami kan sile ninu (ilu naa) fun awon t’o n paya iya eleta-elero
وَفِي مُوسَىٰ إِذْ أَرْسَلْنَاهُ إِلَىٰ فِرْعَوْنَ بِسُلْطَانٍ مُبِينٍ
(Ami tun wa) lara (Anabi) Musa. Nigba ti A fi eri ponnbele ran an nise si Fir‘aon
فَتَوَلَّىٰ بِرُكْنِهِ وَقَالَ سَاحِرٌ أَوْ مَجْنُونٌ
Sugbon (Fir‘aon) gbunri pelu awon omo ogun re. O si wi pe: "Opidan tabi were kan (niyi)

Choose other languages: