Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #41 Translated in Yoruba

وَتَرَكْنَا فِيهَا آيَةً لِلَّذِينَ يَخَافُونَ الْعَذَابَ الْأَلِيمَ
A si fi ami kan sile ninu (ilu naa) fun awon t’o n paya iya eleta-elero
وَفِي مُوسَىٰ إِذْ أَرْسَلْنَاهُ إِلَىٰ فِرْعَوْنَ بِسُلْطَانٍ مُبِينٍ
(Ami tun wa) lara (Anabi) Musa. Nigba ti A fi eri ponnbele ran an nise si Fir‘aon
فَتَوَلَّىٰ بِرُكْنِهِ وَقَالَ سَاحِرٌ أَوْ مَجْنُونٌ
Sugbon (Fir‘aon) gbunri pelu awon omo ogun re. O si wi pe: "Opidan tabi were kan (niyi)
فَأَخَذْنَاهُ وَجُنُودَهُ فَنَبَذْنَاهُمْ فِي الْيَمِّ وَهُوَ مُلِيمٌ
Nitori naa, A mu oun ati awon omo ogun re. A si ju won sinu agbami odo nigba ti o je alabuku
وَفِي عَادٍ إِذْ أَرْسَلْنَا عَلَيْهِمُ الرِّيحَ الْعَقِيمَ
(Ami tun wa) lara ijo ‘Ad. (Ranti) nigba ti A ran ategun iparun si won

Choose other languages: