Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #95 Translated in Yoruba

إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا وَمَاتُوا وَهُمْ كُفَّارٌ فَلَنْ يُقْبَلَ مِنْ أَحَدِهِمْ مِلْءُ الْأَرْضِ ذَهَبًا وَلَوِ افْتَدَىٰ بِهِ ۗ أُولَٰئِكَ لَهُمْ عَذَابٌ أَلِيمٌ وَمَا لَهُمْ مِنْ نَاصِرِينَ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si ku nigba ti won je alaigbagbo, A o nii gba ekun ile wura lowo enikeni ninu won, ibaa fi serapada (fun emi ara re nibi Ina). Awon wonyen ni iya eleta-elero n be fun. Ko si nii si awon oluranlowo fun won
لَنْ تَنَالُوا الْبِرَّ حَتَّىٰ تُنْفِقُوا مِمَّا تُحِبُّونَ ۚ وَمَا تُنْفِقُوا مِنْ شَيْءٍ فَإِنَّ اللَّهَ بِهِ عَلِيمٌ
Owo yin ko le ba oore ayafi ti e ba n na ninu ohun ti e nifee si. Ati pe ohunkohun ti e ba na, dajudaju Allahu ni Onimo nipa re
كُلُّ الطَّعَامِ كَانَ حِلًّا لِبَنِي إِسْرَائِيلَ إِلَّا مَا حَرَّمَ إِسْرَائِيلُ عَلَىٰ نَفْسِهِ مِنْ قَبْلِ أَنْ تُنَزَّلَ التَّوْرَاةُ ۗ قُلْ فَأْتُوا بِالتَّوْرَاةِ فَاتْلُوهَا إِنْ كُنْتُمْ صَادِقِينَ
Gbogbo ounje lo je eto fun awon omo ’Isro’il ayafi eyi ti ’Isro’il ba se ni eewo fun emi ara re siwaju ki A to so at-Taorah kale. So pe: “Nitori naa, e mu at-Taorah wa, ki e si ka a sita ti eyin ba je olododo.”
فَمَنِ افْتَرَىٰ عَلَى اللَّهِ الْكَذِبَ مِنْ بَعْدِ ذَٰلِكَ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الظَّالِمُونَ
Nitori naa, enikeni ti o ba da adapa iro mo Allahu leyin iyen, awon wonyen ni alabosi
قُلْ صَدَقَ اللَّهُ ۗ فَاتَّبِعُوا مِلَّةَ إِبْرَاهِيمَ حَنِيفًا وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
So pe: "Allahu so ododo. Nitori naa, e tele esin (Anabi) ’Ibrohim, oluduro-deede-ninu-’Islam. Ko si si ninu awon osebo

Choose other languages: