Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #98 Translated in Yoruba

فَمَنِ افْتَرَىٰ عَلَى اللَّهِ الْكَذِبَ مِنْ بَعْدِ ذَٰلِكَ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الظَّالِمُونَ
Nitori naa, enikeni ti o ba da adapa iro mo Allahu leyin iyen, awon wonyen ni alabosi
قُلْ صَدَقَ اللَّهُ ۗ فَاتَّبِعُوا مِلَّةَ إِبْرَاهِيمَ حَنِيفًا وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
So pe: "Allahu so ododo. Nitori naa, e tele esin (Anabi) ’Ibrohim, oluduro-deede-ninu-’Islam. Ko si si ninu awon osebo
إِنَّ أَوَّلَ بَيْتٍ وُضِعَ لِلنَّاسِ لَلَّذِي بِبَكَّةَ مُبَارَكًا وَهُدًى لِلْعَالَمِينَ
Dajudaju ile akoko ti A fi lele fun awon eniyan ni eyi ti o wa ni Bakkah . (O je ile) ibukun ati imona fun gbogbo eda
فِيهِ آيَاتٌ بَيِّنَاتٌ مَقَامُ إِبْرَاهِيمَ ۖ وَمَنْ دَخَلَهُ كَانَ آمِنًا ۗ وَلِلَّهِ عَلَى النَّاسِ حِجُّ الْبَيْتِ مَنِ اسْتَطَاعَ إِلَيْهِ سَبِيلًا ۚ وَمَنْ كَفَرَ فَإِنَّ اللَّهَ غَنِيٌّ عَنِ الْعَالَمِينَ
Awon ami t’o yanju wa ninu re; ibuduro (Anabi) ’Ibrohim. Enikeni ti o ba wo inu re ti di eni ifayabale. Allahu se abewo si Ile naa ni dandan fun awon eniyan, t’o lagbara ona ti o maa gba debe. Enikeni ti o ba si sai gbagbo,dajudaju Allahu ni Oloro ti ko bukata si gbogbo eda
قُلْ يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَاللَّهُ شَهِيدٌ عَلَىٰ مَا تَعْمَلُونَ
So pe: "Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu? Allahu si ni Arinu-rode ohun ti e n se nise

Choose other languages: