Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #73 Translated in Yoruba

وَدَّتْ طَائِفَةٌ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ لَوْ يُضِلُّونَكُمْ وَمَا يُضِلُّونَ إِلَّا أَنْفُسَهُمْ وَمَا يَشْعُرُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab fe lati si yin lona. Won ko le si enikeni lona afi ara won, won ko si fura
يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَأَنْتُمْ تَشْهَدُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, e si n jerii (si ododo re)
يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَلْبِسُونَ الْحَقَّ بِالْبَاطِلِ وَتَكْتُمُونَ الْحَقَّ وَأَنْتُمْ تَعْلَمُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi da iro po mo ododo, e si n fi ododo pamo nigba ti eyin mo (ododo)
وَقَالَتْ طَائِفَةٌ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ آمِنُوا بِالَّذِي أُنْزِلَ عَلَى الَّذِينَ آمَنُوا وَجْهَ النَّهَارِ وَاكْفُرُوا آخِرَهُ لَعَلَّهُمْ يَرْجِعُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab wi pe: “E lo gbagbo ninu ohun ti Won sokale fun awon t’o gbagbo ni ododo nibere ojo, ki e si tako o nipari re, boya awon musulumi (kan) maa seri pada (seyin ninu esin ’Islam)
وَلَا تُؤْمِنُوا إِلَّا لِمَنْ تَبِعَ دِينَكُمْ قُلْ إِنَّ الْهُدَىٰ هُدَى اللَّهِ أَنْ يُؤْتَىٰ أَحَدٌ مِثْلَ مَا أُوتِيتُمْ أَوْ يُحَاجُّوكُمْ عِنْدَ رَبِّكُمْ ۗ قُلْ إِنَّ الْفَضْلَ بِيَدِ اللَّهِ يُؤْتِيهِ مَنْ يَشَاءُ ۗ وَاللَّهُ وَاسِعٌ عَلِيمٌ
(Won tun wi pe:) “E ma gbagbo ayafi eni ti o ba tele esin yin.” So pe: “Dajudaju imona (’Islam) ni imona ti Allahu.” (Won tun wi pe:) “(E ma gbagbo) pe won fun eni kan ni iru ohun ti Won fun yin tabi pe won yoo tako yin (ti won yo si jare yin) lodo Oluwa yin.” So pe: “Dajudaju oore ajulo wa ni owo Allahu. O n fun eni ti O ba fe. Allahu ni Olugbaaye, Onimo.”

Choose other languages: