Quran Apps in many lanuages:

Surah Saba Ayahs #29 Translated in Yoruba

قُلْ لَا تُسْأَلُونَ عَمَّا أَجْرَمْنَا وَلَا نُسْأَلُ عَمَّا تَعْمَلُونَ
So pe: “Won ko nii bi yin leere nipa ese ti a da; won ko si nii bi awa naa nipa ohun ti e n se nise.”
قُلْ يَجْمَعُ بَيْنَنَا رَبُّنَا ثُمَّ يَفْتَحُ بَيْنَنَا بِالْحَقِّ وَهُوَ الْفَتَّاحُ الْعَلِيمُ
So pe: “Oluwa wa yoo ko wa jo papo. Leyin naa, O maa fi ododo sedajo laaarin wa. Oun si ni Onidaajo, Onimo.”
قُلْ أَرُونِيَ الَّذِينَ أَلْحَقْتُمْ بِهِ شُرَكَاءَ ۖ كَلَّا ۚ بَلْ هُوَ اللَّهُ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
So pe: “E fi han mi na awon orisa ti e dapo mo Allahu.” Rara (ko ni akegbe). Rara se, Oun ni Alagbara, Ologbon
وَمَا أَرْسَلْنَاكَ إِلَّا كَافَّةً لِلنَّاسِ بَشِيرًا وَنَذِيرًا وَلَٰكِنَّ أَكْثَرَ النَّاسِ لَا يَعْلَمُونَ
A o ran o nise afi si gbogbo eniyan patapata; (o je) oniroo-idunnu ati olukilo sugbon opolopo awon eniyan ko mo
وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا الْوَعْدُ إِنْ كُنْتُمْ صَادِقِينَ
Won si n wi pe: “Igba wo ni adehun yii yoo se ti e ba je olododo?”

Choose other languages: