Quran Apps in many lanuages:

Surah At-Tahrim Ayahs #12 Translated in Yoruba

ضَرَبَ اللَّهُ مَثَلًا لِلَّذِينَ كَفَرُوا امْرَأَتَ نُوحٍ وَامْرَأَتَ لُوطٍ ۖ كَانَتَا تَحْتَ عَبْدَيْنِ مِنْ عِبَادِنَا صَالِحَيْنِ فَخَانَتَاهُمَا فَلَمْ يُغْنِيَا عَنْهُمَا مِنَ اللَّهِ شَيْئًا وَقِيلَ ادْخُلَا النَّارَ مَعَ الدَّاخِلِينَ
Allahu fi iyawo (Anabi) Nuh ati iyawo (Anabi) Lut se apeere fun awon t’o sai gbagbo. Awon mejeeji wa labe erusin meji rere ninu awon erusin Wa. Awon (obinrin) mejeeji si janba awon oko won. Awon oko won ko si fi kini kan ro won loro lodo Allahu. A o si so fun awon obinrin mejeeji pe: "E wo inu Ina pelu awon oluwole (sinu Ina)
وَضَرَبَ اللَّهُ مَثَلًا لِلَّذِينَ آمَنُوا امْرَأَتَ فِرْعَوْنَ إِذْ قَالَتْ رَبِّ ابْنِ لِي عِنْدَكَ بَيْتًا فِي الْجَنَّةِ وَنَجِّنِي مِنْ فِرْعَوْنَ وَعَمَلِهِ وَنَجِّنِي مِنَ الْقَوْمِ الظَّالِمِينَ
Allahu tun fi iyawo Fir‘aon se apeere fun awon t’o gbagbo. Nigba ti o so pe: "Oluwa mi, ko ile kan fun mi lodo Re ninu Ogba Idera. La mi lowo Fir‘aon ati ise owo re. Ki O si la mi lowo ijo alabosi
وَمَرْيَمَ ابْنَتَ عِمْرَانَ الَّتِي أَحْصَنَتْ فَرْجَهَا فَنَفَخْنَا فِيهِ مِنْ رُوحِنَا وَصَدَّقَتْ بِكَلِمَاتِ رَبِّهَا وَكُتُبِهِ وَكَانَتْ مِنَ الْقَانِتِينَ
Ati Moryam omobinrin ‘Imron, eyi ti o so abe re. A si fe ategun si i lara ninu ategun emi ti A da. O gbagbo lododo ninu awon oro Oluwa re ati awon Tira Re. O si wa ninu awon olutele-ase Allahu

Choose other languages: