Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #39 Translated in Yoruba

يُرْسَلُ عَلَيْكُمَا شُوَاظٌ مِنْ نَارٍ وَنُحَاسٌ فَلَا تَنْتَصِرَانِ
Won maa ju eta-para ina ati eta-para ide le eyin mejeeji lori, eyin mejeeji ko si le ran’ra yin lowo
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فَإِذَا انْشَقَّتِ السَّمَاءُ فَكَانَتْ وَرْدَةً كَالدِّهَانِ
Nitori naa, nigba ti sanmo ba faya perepere, o si maa pon wa we bi epo pupa
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فَيَوْمَئِذٍ لَا يُسْأَلُ عَنْ ذَنْبِهِ إِنْسٌ وَلَا جَانٌّ
Nitori naa, ni ojo yen Won o nii bi eniyan ati alujannu kan leere nipa ese re; (o ti wa ni akosile ni odo Wa)

Choose other languages: