Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #41 Translated in Yoruba

فَإِذَا انْشَقَّتِ السَّمَاءُ فَكَانَتْ وَرْدَةً كَالدِّهَانِ
Nitori naa, nigba ti sanmo ba faya perepere, o si maa pon wa we bi epo pupa
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فَيَوْمَئِذٍ لَا يُسْأَلُ عَنْ ذَنْبِهِ إِنْسٌ وَلَا جَانٌّ
Nitori naa, ni ojo yen Won o nii bi eniyan ati alujannu kan leere nipa ese re; (o ti wa ni akosile ni odo Wa)
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
يُعْرَفُ الْمُجْرِمُونَ بِسِيمَاهُمْ فَيُؤْخَذُ بِالنَّوَاصِي وَالْأَقْدَامِ
Won maa mo awon elese pelu ami ara won. Won si maa fi aaso ori ati ese gba won mu

Choose other languages: