Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #33 Translated in Yoruba

يَسْأَلُهُ مَنْ فِي السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ كُلَّ يَوْمٍ هُوَ فِي شَأْنٍ
Awon t’o wa ninu awon sanmo ati ile n beere (nnkan) lodo Re; O si wa lori ise lojoojumo
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
سَنَفْرُغُ لَكُمْ أَيُّهَ الثَّقَلَانِ
A oo mu tiyin gbo (lojo esan), eyin eniyan ati alujannu
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
يَا مَعْشَرَ الْجِنِّ وَالْإِنْسِ إِنِ اسْتَطَعْتُمْ أَنْ تَنْفُذُوا مِنْ أَقْطَارِ السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ فَانْفُذُوا ۚ لَا تَنْفُذُونَ إِلَّا بِسُلْطَانٍ
Eyin awujo alujannu ati eniyan, ti e ba lagbara lati sa jade ninu awon agbegbe sanmo ati ile, e sa jade. E o le sa jade afi pelu agbara

Choose other languages: