Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #13 Translated in Yoruba

وَأَقِيمُوا الْوَزْنَ بِالْقِسْطِ وَلَا تُخْسِرُوا الْمِيزَانَ
E gbe osuwon naa duro pelu dogbadogba. Ki e si ma se din osuwon ku
وَالْأَرْضَ وَضَعَهَا لِلْأَنَامِ
Ile, (Allahu) te e sile fun awon eda
فِيهَا فَاكِهَةٌ وَالنَّخْلُ ذَاتُ الْأَكْمَامِ
Eso ati dabinu alapo wa lori (ile)
وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

Choose other languages: