Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #16 Translated in Yoruba

وَالْحَبُّ ذُو الْعَصْفِ وَالرَّيْحَانُ
Ati eso koro onipoporo ati elewe dudu (wa lori ile)
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
خَلَقَ الْإِنْسَانَ مِنْ صَلْصَالٍ كَالْفَخَّارِ
(Allahu) seda eniyan lati ara amo gbigbe t’o n dun kokoko bi ikoko amo
وَخَلَقَ الْجَانَّ مِنْ مَارِجٍ مِنْ نَارٍ
O si seda alujannu lati ara ahon ina ti ko ni eefin
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

Choose other languages: